Numbers 4:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iye wọ́n jẹ́ ẹgbẹrinla ó dín aadọta (2,750).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a si kà ninu wọn nipa idile wọn jẹ́ ẹgbẹrinla o din ãdọta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye wọn nípa ìdílé jẹ́ ẹgbẹ̀rìnlá ó dín àádọ́ta (2,750).