Numbers 4:45 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èyí ni iye àwọn tí Mose ati Aaroni kà ninu àwọn ọmọ Merari gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi li awọn ti a kà ninu idile awọn ọmọ Merari, ti Mose ati Aaroni kà gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA nipa ọwọ́ Mose.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Mérárì. Mósè àti Árónì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLÚWA láti ẹnu Mósè.