Numbers 4:46 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí Mose, Aaroni ati àwọn olórí àwọn ọmọ Israẹli kà ninu àwọn ọmọ Lefi ní ìdílé-ìdílé gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ti a kà ninu awọn ọmọ Lefi, ti Mose ati Aaroni ati awọn olori Israeli kà, nipa idile wọn, ati gẹgẹ bi ile baba wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni Mósè, Árónì àti olórí ìjọ ènìyàn ka gbogbo ọmọ Léfì nípa ìdílé àti ilé baba wọn.