Numbers 4:48 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
jẹ́ ẹgbaarin ó lé ẹgbẹta ó dín ogún (8,580).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgbẹtalelẹgbarin o din ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá lé lẹ́gbàarin ó dín ogún (8,580).