Numbers 8:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mose ati Aaroni ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sì ya àwọn ọmọ Lefi sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose pé kí wọ́n ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni Mose, ati Aaroni, ati gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, ṣe si awọn ọmọ Lefi: gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA paṣẹ fun Mose niti awọn ọmọ Lefi, bẹ̃li awọn ọmọ Israeli ṣe si wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè, Árónì àti gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì sì ṣe fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mósè.