Numbers 9:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìkùukùu ni lọ́sàn-án, ṣugbọn ní alẹ́, ó dàbí ọ̀wọ̀n iná. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì máa ń rí nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li o si ri nigbagbogbo: awọsanma bò o, ati oye iná li oru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ló sì ṣe títí, ìkúùkù yóò bò ó lọ́sán, ìrísí rẹ̀ sì dàbí iná lálẹ́.