Obadiah 1:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí ìwà ìkà tí ẹ hù sí àwọn ọmọ Israẹli, arakunrin yín, ojú yóo tì yín a óo sì pa yín run títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ìwa-ipa si Jakobu arakunrin rẹ itiju yio bò ọ, a o si ke ọ kuro titi lai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwà ipá sí Jákọ́bù arákùnrin rẹ, ìtìjú yóò bò ọ, a ó sì pa ọ run títí láé.