Obadiah 1:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O kì bá tí dúró sí oríta, kí o máa mú àwọn tí wọn ń gbìyànjú láti sá àsálà; o kì bá tí fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni iwọ kì ba ti duro ni ikorita lati ké awọn tirẹ̀ ti o ti salà kuro; bẹ̃ni iwọ kì ba ti sé awọn tirẹ̀ ti o kù li ọjọ wahala mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà láti ké àwọn tirẹ̀ tó ti sálà kúrò. Ìwọ kì bá tí fa àwọn tó sẹ́kù wọn lélẹ̀ ní ọjọ́ wàhálà wọn.

Recommended Reading