Obadiah 1:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ọjọ́ ìdájọ́ OLUWA fẹ́rẹ̀ dé sórí àwọn orílẹ̀-èdè; a óo san án fún ọ, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Ohun tí o bá ṣe, yóo pada sí orí ara rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọjọ Oluwa kù si dẹdẹ sori gbogbo awọn keferi: bi iwọ ti ṣe, bẹ̃li a o si ṣe si ọ: ẹsan rẹ yio si yipada sori ara rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí ọjọ́ OLÚWA súnmọ́ etílé lórí gbogbo àwọn aláìkọlà. Bí ìwọ ti se, bẹ́ẹ̀ ni a ó se sí ìwọ náà; ẹ̀san rẹ yóò sì yípadà sí orí ara rẹ.