Obadiah 1:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin eniyan mi, bí ẹ ti jìyà ní òkè mímọ́ mi, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè náà yóo jìyà; wọn óo jìyà yóo tẹ́ wọn lọ́rùn, wọn yóo sì wà gẹ́gẹ́ bí ẹni pé wọn kò sí rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bi ẹnyin ti mu lori oke mimọ́ mi, bẹ̃ni gbogbo awọn keferi yio ma mu titi, nitõtọ, nwọn o mu, nwọn o si gbemì, nwọn o si wà bi ẹnipe nwọn kò ti si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀ se mu lórí òkè mímọ́ mi Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo aláìkọlà yóò máa mu títí Wọn yóò mu wọn yóò sì gbémì Wọn yóò sì wà bí ẹni pé wọn kò wà rí