Obadiah 1:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ṣugbọn ní òkè Sioni ni àwọn tí wọ́n bá sá àsálà yóo máa gbé, yóo sì jẹ́ òkè mímọ́; àwọn ọmọ Jakọbu yóo gba ohun ìní wọn pada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn igbala yio wà lori oke Sioni, yio si jẹ mimọ́, awọn ara ile Jakobu yio si ni ini wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Síónì Wọn yóò sì jẹ́ mímọ́ àti ilé Jákọ́bù yóò sì ní ìní wọn