Obadiah 1:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọn ń gbé Nẹgẹbu yóo gba òkè Edomu, àwọn tí wọ́n wà ní ẹsẹ̀ Ṣefela yóo gba ilẹ̀ àwọn ará Filistia; wọn yóo gba gbogbo agbègbè Efuraimu ati ilẹ̀ Samaria, àwọn ará Bẹnjamini yóo sì gba ilẹ̀ Gileadi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ara gusu yio ni oke Esau; awọn ti pẹ̀tẹlẹ yio si ni awọn ara Filistia: nwọn o si ni oko Efraimu, ati oko Samaria: Benjamini yio si ni Gileadi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará Gúsù yóò ni òkè Ísọ̀, àwọn ará ẹsẹ̀ òkè yóò ni ilẹ̀ àwọn ará Fílísítíánì ní ìní. Wọn yóò sì ni oko Éfúráímù àti Samáríà; Bẹ́ńjámínì yóò ní Gílíádì ní ìní.