Obadiah 1:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù; gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, mo ti sọ iwọ di kekere larin awọn keferi: iwọ di gigàn lọpọlọpọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kíyèsí i, Èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrin àwọn aláìkọlà; ìwọ yóò sì di gígàn lọ́pọ̀lọpọ̀,