Obadiah 1:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Hala wọ́n óo gba ilẹ̀ Fonike títí dé Sarefati; àwọn eniyan Jerusalẹmu tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Sefaradi yóo gba àwọn ìlú tí ó wà ní Nẹgẹbu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati igbèkun ogun yi, ti awọn ọmọ Israeli ti o wà larin awọn ara Kenaani, titi de Sarefati; ati igbèkun Jerusalemu ti o wà ni Sefaradi, yio ni awọn ilu nla gusu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìgbèkùn Ísírẹ́lì tí ó wà ní Kénánì yóò ni ilẹ̀ títí dé Séréfátì; àwọn ìgbékùn láti Jérúsálẹ́mù tí ó wà ní Séfárádì yóò ni àwọn ìlú Gúsù ní ìní