Obadiah 1:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni, wọn yóo jọba lórí òkè Edomu; ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn olugbala yio si goke Sioni wá lati ṣe idajọ oke Esau; ijọba na yio si jẹ ti Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn olùgbàlà yóò sì gòkè Síónì wá láti jọba lé orí àwọn òkè Ísọ̀. Ìjọba náà yóò sì jẹ́ ti OLÚWA.