Obadiah 1:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogun ti kó Esau, gbogbo ìṣúra rẹ̀ ni wọ́n ti kó tán!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bawo li a ti ṣawari awọn nkan Esau! bawo li a ti wá awọn ohun ikọkọ rẹ̀ jade!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báwo ni a ṣe se àwárí nǹkan Ísọ̀ tí a sì wá ohun ìní ìkọ̀kọ̀ rẹ̀ jáde