Obadiah 1:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ní ọjọ́ náà, ni n óo pa àwọn ọlọ́gbọ́n run ní Edomu, òye wọn yóo sì di òfo ní òkè Esau.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa wipe, li ọjọ na ki emi o run awọn ọlọgbọn kuro ni Edomu, ati imoye kuro li oke Esau?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA wí pé, “Ní ọjọ́ náà, Èmi yóò pa àwọn ọlọ́gbọ́n Édómù run, àti àwọn amòye run kúrò ní òkè Ísọ̀?