Obadiah 1:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ ìlú Temani, ìbẹ̀rùbojo yóo dé bá àwọn akọni rẹ, gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní òkè Esau ni a óo sì fi idà pa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alagbara rẹ yio si bẹ̀ru, iwọ Temani, nitori ki a le ke olukuluku ti ori oke Esau kuro nitori ipania.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, Ìwọ Témánì, gbogbo àwọn tó wà ní orí òkè Ísọ̀ ní a ó gé kúrò nínú ìpànìyàn náà.