Philippians 1:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn ó tún ṣàǹfààní bí mo bá wà láàyè ninu ẹran-ara, nítorí tiyín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sibẹ lati wà ninu ara jẹ anfani nitori ti nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó ṣe iyebíye fún yín kí èmi kí ó wà nínú ara.