Philippians 1:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí láti ìbẹ̀rẹ̀ títí di àkókò yìí ni ẹ ti ń bá mi ṣiṣẹ́ pọ̀ ninu iṣẹ́ ìyìn rere.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ìdapọ nyin ninu ihinrere lati ọjọ kini wá titi fi di isisiyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí ìdàpọ̀ yín nínú ìyìn rere láti ọjọ́ kìn-ín-ni wá títí di ìsinsinyìí.