Philippians 2:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kí ẹ lè jẹ́ Ọmọ Ọlọrun, tí kò lẹ́bi tí kò sì ní àléébù, ọmọ Ọlọrun tí ó pé, láàrin àwọn ìran tí ọ̀nà wọn wọ́, tí ìwà wọn sì ti bàjẹ́. Láàrin irú àwọn eniyan wọnyi ni ẹ̀ ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ ninu ayé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ẹnyin ki o le jẹ alailẹgàn ati oniwa tutu, ọmọ Ọlọrun, alailabawọn, larin oniwà wíwọ ati alarekereke orilẹ-ede, larin awọn ẹniti a nri nyin bi imọlẹ li aiye;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ẹ̀yin lè jẹ́ aláìlẹ́gàn àti oníwà mímọ́, mọ Ọlọ́run, aláìlábàwọ́n, láàrin oníwà wíwọ́ àti alárèékérekè orílẹ̀-èdè láàrin àwọn ẹni tí a ń rí yín bí ìmọ́lẹ̀ ní ayé.