Philippians 2:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ máa ní èrò yìí ninu ara yín, irú èyí tí ó wà ninu Kristi Jesu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ni ero yi ninu nyin, eyi ti o ti wà pẹlu ninu Kristi Jesu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìṣe yín gbọdọ̀ dàbí ti Kírísítì Jésù: