Philippians 2:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà ni Ọlọrun ṣe gbé e ga ju ẹnikẹ́ni lọ; ó sì fún un ní orúkọ tí ó ga ju gbogbo orúkọ yòókù lọ,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina Ọlọrun pẹlu si ti gbé e ga gidigidi, o si ti fi orukọ kan fun u ti o bori gbogbo orukọ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Ọlọ́run ti gbé e ga sí ìpele tí ó ga jùlọ, ó sì ti fi orúkọ kan ti ó borí gbogbo orúkọ: