Philippians 3:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ kẹjọ ni wọ́n kọ mí nílà. Ọmọ Israẹli ni mí, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini, Heberu paraku ni mí. Nípa ti Òfin Mose, Farisi ni mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti a kọ nilà ni ijọ kẹjọ, lati inu kukuté Israeli wá, lati inu ẹ̀ya Benjamini, Heberu lati inu Heberu wá; niti ofin, Farisi li emi;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnii tí a kọ nílà ní ijọ́ kẹjọ, láti inú kùkùté Ísírẹ́lì wá, láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Hébérù láti inú Hébérù wá; nítorí, ní ti òfin Farisí ni èmi;