Philippians 4:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ kí gbogbo àwọn eniyan Ọlọrun tí ó jẹ́ ti Kristi Jesu. Àwọn arakunrin tí ó wà lọ́dọ̀ mi ki yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ kí olukuluku enia mimọ́ ninu Kristi Jesu. Awọn ara ti o wà pẹlu mi kí nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ kí olukùlùkù ènìyàn-mímọ́ nínú Kírísítì Jésù. Àwọn ará tí ó wà pẹ̀lú mi kí yín.