Philippians 4:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa Jesu Kristi kí ó wà pẹlu ẹ̀mí yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa, ki o wà pẹlu ẹmi nyin. Amin.A kọ ọ si awọn ara Filippi lati Romu lọ lati ọwọ́ Epafroditu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Oore-ọ̀fẹ́ Jésù Kírísítì Olúwa wa, kí ó wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín. Àmín.