Proverbs 1:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kí àwọn eniyan lè ní ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́, kí òye ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lè yé wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati mọ̀ ọgbọ́n ati ẹkọ́; lati mọ̀ ọ̀rọ oye;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́ Láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀