Proverbs 1:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé mo ti ké títí, kò sì sí ẹni tí ó gbọ́, mo ti na ọwọ́ si yín ṣugbọn kò sí ẹni tí ó dá mi lóhùn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti emi pè, ti ẹnyin si kọ̀; ti emi nà ọwọ mi, ti ẹnikan kò si kà a si:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n níwọ̀n bí ẹ ti kọ ìpè ní ìgbà tí mo pè kò sì sí ẹni tí ó kọ ibi ara sí mi gbà tí mo háwọ́ sí wọn,