Proverbs 1:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ẹ ti pa gbogbo ìmọ̀ràn mi tì, ẹ kò sì gbọ́ ọ̀kankan ninu ìbáwí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹnyin ti ṣá gbogbo ìgbimọ mi tì, ẹnyin kò si fẹ ibawi mi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níwọ̀n bí ẹ ti kọ gbogbo ìmọ̀ràn mi tí ẹ kò sì ní gba ìbáwí mi