Proverbs 1:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Èmi náà óo sì máa fi yín rẹ́rìn-ín nígbà tí ìdààmú bá dé ba yín, n óo máa fi yín ṣe ẹlẹ́yà nígbà tí ìpayà bá dé ba yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi pẹlu o rẹrin idãmu nyin; emi o ṣe ẹ̀fẹ nigbati ibẹ̀ru nyin ba de;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi pẹ̀lú yóò fi ìdààmú yín rẹ́rìn-ín N ó sẹ̀fẹ̀ nígbà tí ìyọnu bá dé bá a yín