Proverbs 1:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ẹ óo jèrè iṣẹ́ yín, ìwà burúkú yín yóo sì di àìsàn si yín lára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni nwọn o ṣe ma jẹ ninu ère ìwa ara wọn, nwọn o si kún fun ìmọkimọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò jẹ èrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn wọn yóò sì jèrè èso ètè wọn ní kíkún