Proverbs 1:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn aláìgbọ́n kú nítorí pé wọn kò gba ẹ̀kọ́ aibikita àwọn òmùgọ̀ ni yóo pa wọ́n run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe irọra awọn alaimọ̀kan ni yio pa wọn, ati alafia awọn aṣiwere ni yio pa wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìrìnkurìn àwọn aláìmọ́kan ni yóò pa wọ́n ìkáwọ́-gbera aláìgbọ́n ni yóò pa á run;