Proverbs 1:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn ẹni tí ó gbọ́ tèmi, yóo máa wà láìléwu, yóo máa gbé pẹlu ìrọ̀rùn, láìsí ìpayà ibi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba fetisi mi yio ma gbe lailewu, yio si farabalẹ kuro ninu ibẹ̀ru ibi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ẹnìkan tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwu yóò sì wà nínú ìdẹ̀ra, láì sí ìbẹ̀rù ìpalára.”