Proverbs 11:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni ìríra ni àwọn alágàbàgebè lójú OLUWA, ṣugbọn àwọn tí ọ̀nà wọn mọ́ ni ìdùnnú fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti iṣe alarekereke aiya, irira ni loju Oluwa; ṣugbọn inu rẹ̀ dùn si awọn aduroṣinṣin:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA kórìíra àwọn ènìyàn ọlọ́kàn búburú ṣùgbọ́n ó ní inú dídùn sí àwọn tí ọ̀nà wọn kò lábùkù.