Proverbs 11:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dájúdájú ẹni ibi kò ní lọ láìjìyà, ṣugbọn a óo gba àwọn olódodo là.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi a tilẹ fi ọwọ so ọwọ, enia buburu kì yio lọ laijiya, ṣugbọn iru-ọmọ olododo li a o gbàla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mọ èyí dájú pé: ènìyàn búburú kì yóò lọ láì jìyà, ṣùgbọ́n àwọn Olódodo yóò lọ láì jìyà.