Proverbs 14:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Eniyan lè máa rẹ́rìn-ín, kí inú rẹ̀ má dùn, ìbànújẹ́ sì le gbẹ̀yìn ayọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ẹrín pẹlu, aiya a ma kãnu; ati li opin, ayọ̀ a di ibinujẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kódà nígbà tí a ń rẹ́rìnín, ọkàn leè máa kérora; ayọ̀ sì leè yọrí sí ìbànújẹ́.