Proverbs 14:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn aládùúgbò talaka pàápàá kórìíra rẹ̀, ṣugbọn ọlọ́rọ̀ a máa ní ọpọlọpọ ọ̀rẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A tilẹ korira talaka lati ọdọ aladugbo rẹ̀ wá: ṣugbọn ọlọrọ̀ ni ọrẹ́ pupọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kódà àwọn aládùúgbò o talákà kò fẹ́ràn rẹ̀ ṣùgbọ́n, Ọlọ́rọ̀ ní ọ̀rẹ́ púpọ̀.