Proverbs 14:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọn ń pète ibi ti ṣìnà, ṣugbọn àwọn tí wọn ń gbèrò ire yóo rí ojurere ati òtítọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti ngbìmọ buburu kò ha ṣina bi? ṣugbọn ãnu ati otitọ ni fun awọn ti ngbìmọ ire.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ àwọn tí ń pète ibi kì í sìnà? Ṣùgbọ́n àwọn tí ń gbérò ohun rere ń rí ìfẹ́ àti òtítọ́.