Proverbs 14:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kò sí iṣẹ́ kan tí kò lérè, ṣugbọn ọ̀rọ̀ ẹnu lásán láìsí iṣẹ́, a máa sọ eniyan di aláìní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu gbogbo lãla li ère pupọ wà: ṣugbọn ọ̀rọ-ẹnu, lasan ni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo iṣẹ́ àṣekára ló máa ń mú èrè wá ṣùgbọ́n ẹjọ́ rírò lásán máa ń ta ni lósì ni.