Proverbs 14:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọgbọ́n ni adé àwọn ọlọ́gbọ́n, ṣugbọn ìwà aláìgbọ́n jẹ́ yẹ̀yẹ́ àwọn òmùgọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Adé awọn ọlọgbọ́n li ọrọ̀ wọn: ṣugbọn iwère awọn aṣiwère ni wère.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọrọ̀ Ọlọgbọ́n ènìyàn ni adé orí wọn ṣùgbọ́n ìwà aláìgbọ́n ń mú ìwà òmùgọ̀ wá.