Proverbs 14:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ìbẹ̀rù OLUWA ni igbẹkẹle tí ó dájú wà, níbẹ̀ ni ààbò wà fún àwọn ọmọ ẹni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni ibẹ̀ru Oluwa ni igbẹkẹle ti o lagbara: yio si jẹ ibi àbo fun awọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó bẹ̀rù OLÚWA ni ilé ìṣọ́ ààbò yóò sì tún jẹ́ ààbò fún àwọn ọmọ rẹ̀.