Proverbs 14:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọgbọ́n kún inú ẹni tí ó mòye, ṣugbọn kò sí ohun tí ó jọ ọgbọ́n lọ́kàn òmùgọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọgbọ́n fi idi kalẹ li aiya ẹniti o moye; ṣugbọn a fi i hàn laiya awọn aṣiwère.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọgbọ́n wà nínú ọkàn olóye kódà láàrin àwọn aláìlóye, ó jẹ́ kí wọn mọ òun.