Proverbs 14:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ohun tí ó jẹ́ ọgbọ́n fún ọlọ́gbọ́n ni pé kí ó kíyèsí ọ̀nà ara rẹ̀, ṣugbọn àìmòye àwọn òmùgọ̀ kún fún ìtànjẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọgbọ́n amoye ni ati moye ọ̀na rẹ̀: ṣugbọn iwere awọn aṣiwere li ẹ̀tan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọgbọ́n olóye ni láti ronú jinlẹ̀ nípa ọ̀nà an wọn ṣùgbọ́n ìwà òmùgọ̀ asìwèrè ni ìtànjẹ.