Proverbs 17:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí kí eniyan ya odò tí wọn sé, dá a dúró kí ó tó di ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o daju fun omi dabi olupilẹṣẹ ìja; nitorina fi ìja silẹ ki o to di nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bíbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí ẹni tí ó dá ojú fún adágún omi nítorí náà mẹ́nu kúrò nínú ọ̀rọ̀ kí ó tó di ìjà.