Proverbs 17:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Owó kò wúlò lọ́wọ́ òmùgọ̀ pé kí ó fi ra ọgbọ́n, nígbà tí kò ní òye?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori kini iye owo yio ṣe wà lọwọ aṣiwère lati rà ọgbọ́n, sa wò o, kò ni oye?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ni ìwúlò owó lọ́wọ́ aṣiwèrè níwọ̀n bí kò ti ní èròńgbà láti rí ọgbọ́n?