Proverbs 17:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kò tọ̀nà láti fi ipá mú aláìṣẹ̀ san owó ìtanràn, nǹkan burúkú ni kí á na gbajúmọ̀ tí kò rú òfin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu kò dara ki a ṣẹ́ olotitọ ni iṣẹ́, tabi ki a lu ọmọ-alade nitori iṣedẽde.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò dára láti fìyà jẹ ènìyàn tí kò ṣẹ̀ tàbí láti na ìjòyè lórí òtítọ́ inú wọn.