Proverbs 18:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni tí ó bá kọ́kọ́ rojọ́ níí dàbí ẹni tí ó jàre, títí tí ẹnìkejì yóo fi bi í ní ìbéèrè,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikini ninu ẹjọ rẹ̀ a dabi ẹnipe o jare, ṣugbọn ẹnikeji rẹ̀ a wá, a si hudi rẹ̀ silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó kọ́kọ́ rojọ́ máa ń dàbí i pé ó jàre títí ẹlòmíràn yóò fi bọ́ síwájú kí ó sì tú àsírí gbogbo.