Proverbs 19:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìgbádùn kò yẹ òmùgọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò yẹ kí ẹrú jọba lórí àwọn ìjòyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun rere kò yẹ fun aṣiwère; tabi melomelo fun iranṣẹ lati ṣe olori awọn ijoye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò yẹ aláìgbọ́n láti máa gbé nínú ọlá ńlá, mélòó mélòó bí ó ti burú tó fún ẹrú láti jọba lórí ọmọ aládé.