Proverbs 19:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọpọlọpọ ni èrò tí ó wà lọ́kàn ọmọ eniyan, ṣugbọn ìfẹ́ OLUWA ni àṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ete pupọ li o wà li aiya enia; ṣugbọn ìgbimọ Oluwa, eyini ni yio duro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn ṣùgbọ́n ìfẹ́ OLÚWA ní ó máa ń borí.