Proverbs 19:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọrọ̀ a máa mú kí eniyan ní ọpọlọpọ ọ̀rẹ́ titun, ṣugbọn àwọn ọ̀rẹ́ talaka a máa kọ̀ ọ́ sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrọ̀ fà ọrẹ́ pupọ; ṣugbọn talaka di yiyà kuro lọdọ aladugbo rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọrọ̀ má a ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀; ṣùgbọ̀n ọ̀rẹ́ ẹ talákà tún kọ̀ ọ́ sílẹ̀.